Esek 33:18 YCE

18 Nigbati olododo ba yipada kuro ninu ododo rẹ̀ ti o si ṣe aiṣedẽde, on o ti ipa rẹ̀ kú.

Ka pipe ipin Esek 33

Wo Esek 33:18 ni o tọ