Esek 33:7 YCE

7 Bẹ̃ni, iwọ ọmọ enia, emi ti fi ọ ṣe oluṣọ́ fun ile Israeli; nitorina iwọ o gbọ́ ọ̀rọ li ẹnu mi, iwọ o si kìlọ fun wọn lati ọdọ mi.

Ka pipe ipin Esek 33

Wo Esek 33:7 ni o tọ