Esek 34:21 YCE

21 Nitoriti ẹnyin ti fi ẹgbẹ́ ati ejiká gbún, ti ẹ si ti fi iwo nyin kàn gbogbo awọn ti o li àrun titi ẹ fi tú wọn kakiri.

Ka pipe ipin Esek 34

Wo Esek 34:21 ni o tọ