Esek 34:30 YCE

30 Bayi ni nwọn o mọ̀ pe emi Oluwa Ọlọrun wọn wà pẹlu wọn, ati awọn, ile Israeli, jẹ enia mi, li Oluwa Ọlọrun wi.

Ka pipe ipin Esek 34

Wo Esek 34:30 ni o tọ