Esek 36:12 YCE

12 Nitõtọ, emi o mu ki enia rìn lori nyin, ani Israeli enia mi; nwọn o si ni ọ, iwọ o si jẹ iní wọn, iwọ kì yio si gbà wọn li ọmọ mọ lati isisiyi lọ.

Ka pipe ipin Esek 36

Wo Esek 36:12 ni o tọ