Esek 36:25 YCE

25 Nigbana ni emi o fi omi mimọ́ wọ́n nyin, ẹnyin o si mọ́: emi o si wẹ̀ nyin mọ́ kuro ninu gbogbo ẹgbin nyin ati kuro ninu gbogbo oriṣa nyin.

Ka pipe ipin Esek 36

Wo Esek 36:25 ni o tọ