28 Ẹnyin o si ma gbe ilẹ ti emi fi fun awọn baba nyin; ẹnyin o si ma jẹ enia mi, emi o si ma jẹ Ọlọrun nyin.
Ka pipe ipin Esek 36
Wo Esek 36:28 ni o tọ