Esek 36:35 YCE

35 Nwọn o si wipe, Ilẹ yi ti o ti di ahoro ti dabi ọgbà Edeni; ati ilu ti o tú, ti o di ahoro, ti o si parun, di ilu olodi, o si ni olugbe.

Ka pipe ipin Esek 36

Wo Esek 36:35 ni o tọ