Esek 4:8 YCE

8 Si kiyesi i, emi o fi idè le ara rẹ, iwọ ki yio si yipada lati ihà kan de ekeji, titi iwọ o fi pari gbogbo ọjọ didotì rẹ.

Ka pipe ipin Esek 4

Wo Esek 4:8 ni o tọ