Esek 40:11 YCE

11 O si wọ̀n ibu abawọle ẹnu-ọ̀na na, igbọnwọ mẹwa; ati gigùn ẹnu-ọ̀na na, igbọnwọ mẹtala.

Ka pipe ipin Esek 40

Wo Esek 40:11 ni o tọ