Esek 40:28 YCE

28 O si mu mi wá si agbalá ti inu nipa ẹnu-ọ̀na gusu: o si wọ̀n ẹnu-ọ̀na gusu na gẹgẹ bi ìwọn wọnyi;

Ka pipe ipin Esek 40

Wo Esek 40:28 ni o tọ