Esek 44:27 YCE

27 Ati li ọjọ ti yio lọ si ibi-mimọ́, si agbalá ti inu, lati ṣe iranṣẹ ni ibi-mimọ́, on o rú ọrẹ ẹbọ ẹ̀ṣẹ rẹ̀, ni Oluwa Ọlọrun wi.

Ka pipe ipin Esek 44

Wo Esek 44:27 ni o tọ