Esek 7:22 YCE

22 Oju mi pẹlu li emi o yipada kuro lọdọ wọn, nwọn o si ba ibi ikọkọ mi jẹ; nitori awọn ọlọṣà yio wọ inu rẹ̀, nwọn o si bà a jẹ.

Ka pipe ipin Esek 7

Wo Esek 7:22 ni o tọ