Jer 1:11 YCE

11 Ọ̀rọ Oluwa si tọ̀ mi wá wipe, Jeremiah, kini iwọ ri? emi si wipe, mo ri ọpa igi almondi.

Ka pipe ipin Jer 1

Wo Jer 1:11 ni o tọ