Jer 1:19 YCE

19 Ṣugbọn nwọn o ba ọ jà, nwọn kì o si le bori rẹ; nitori emi wà pẹlu rẹ, li Oluwa wi, lati gbà ọ.

Ka pipe ipin Jer 1

Wo Jer 1:19 ni o tọ