Jer 10:16 YCE

16 Ipin Jakobu kò si dabi wọn nitori on ni iṣe Ẹlẹda ohun gbogbo; Israeli si ni ẹya ijogun rẹ̀: Oluwa awọn ọmọ-ogun li orukọ rẹ̀.

Ka pipe ipin Jer 10

Wo Jer 10:16 ni o tọ