Jer 10:18 YCE

18 Nitori bayi li Oluwa wi, sa wò o, emi o gbọ̀n awọn olugbe ilẹ na nù lẹ̃kan yi, emi o si pọ́n wọn loju, ki nwọn ki o le ri i.

Ka pipe ipin Jer 10

Wo Jer 10:18 ni o tọ