23 Oluwa! emi mọ̀ pe, ọ̀na enia kò si ni ipa ara rẹ̀: kò si ni ipá enia ti nrin, lati tọ́ iṣisẹ rẹ̀.
Ka pipe ipin Jer 10
Wo Jer 10:23 ni o tọ