Jer 12:12 YCE

12 Awọn abanijẹ ti gori gbogbo ibi giga wọnni ni ọ̀dan, nitori idà Oluwa yio pa lati ikangun de ikangun ekeji ilẹ na, alafia kò si fun gbogbo alãye.

Ka pipe ipin Jer 12

Wo Jer 12:12 ni o tọ