Jer 12:17 YCE

17 Ṣugbọn bi nwọn kì o gbọ́, emi o fà orilẹ-ède na tu patapata; emi o si pa wọn run, li Oluwa wi.

Ka pipe ipin Jer 12

Wo Jer 12:17 ni o tọ