Jer 13:4 YCE

4 Mu amure ti iwọ ti rà, ti o wà li ẹgbẹ rẹ, ki o si dide, lọ si odò Ferate, ki o si fi i pamọ nibẹ, ninu pàlapála okuta.

Ka pipe ipin Jer 13

Wo Jer 13:4 ni o tọ