Jer 15:13 YCE

13 Ohun-ini ati iṣura rẹ li emi o fi fun ijẹ, li aigbowo, nitori gbogbo ẹ̀ṣẹ rẹ ni àgbegbe rẹ.

Ka pipe ipin Jer 15

Wo Jer 15:13 ni o tọ