Jer 15:3 YCE

3 Emi si fi iru ijiya mẹrin sori wọn, li Oluwa wi, idà lati pa, ajá lati wọ́ kiri, ẹiyẹ oju-ọrun ati ẹranko ilẹ, lati jẹ, ati lati parun.

Ka pipe ipin Jer 15

Wo Jer 15:3 ni o tọ