Jer 15:6 YCE

6 Iwọ ti kọ̀ mi silẹ, li Oluwa wi, iwọ ti pada sẹhin; nitorina emi o ná ọwọ mi si ọ, emi o si pa ọ run; ãrẹ̀ mu mi lati ṣe iyọnu.

Ka pipe ipin Jer 15

Wo Jer 15:6 ni o tọ