Jer 17:1 YCE

1 Ẹ̀ṢẸ Juda ni a fi kalamu irin kọ, a fi ṣonṣo okuta adamante gbẹ ẹ sori walã aiya wọn, ati sori iwo pẹpẹ nyin.

Ka pipe ipin Jer 17

Wo Jer 17:1 ni o tọ