Jer 17:5 YCE

5 Bayi li Oluwa wi: Egbe ni fun ẹniti o gbẹkẹle enia, ti o fi ẹlẹran ara ṣe apá rẹ̀, ẹniti ọkàn rẹ̀ si ṣi kuro lọdọ Oluwa!

Ka pipe ipin Jer 17

Wo Jer 17:5 ni o tọ