Jer 18:8 YCE

8 Bi orilẹ-ède na ti mo ti sọ ọ̀rọ si ba yipada kuro ninu ìwa-buburu rẹ̀, emi o yi ọkàn mi pada niti ibi ti emi ti rò lati ṣe si wọn.

Ka pipe ipin Jer 18

Wo Jer 18:8 ni o tọ