Jer 2:37 YCE

37 Lõtọ iwọ o kuro lọdọ rẹ̀, iwọ o si ka ọwọ le ori, nitori Oluwa ti kọ̀ awọn onigbẹkẹle rẹ, iwọ kì yio si ṣe rere ninu wọn.

Ka pipe ipin Jer 2

Wo Jer 2:37 ni o tọ