10 Nitori emi ti yi oju mi si ilu yi fun ibi, kì isi iṣe fun rere, li Oluwa wi: a o fi i le ọba Babeli lọwọ, yio fi iná kun u.
Ka pipe ipin Jer 21
Wo Jer 21:10 ni o tọ