Jer 21:13 YCE

13 Wò o, Emi doju kọ nyin, olugbe afonifoji, ati ti okuta pẹtẹlẹ, li Oluwa wi, ẹnyin ti o wipe, Tani yio kọlu wa? ati tani yio wọ̀ inu ibugbe wa?

Ka pipe ipin Jer 21

Wo Jer 21:13 ni o tọ