Jer 22:20 YCE

20 Goke lọ si Lebanoni, ki o si ke, ki o si gbe ohùn rẹ soke ni Baṣani, ki o kigbe lati Abarimu, nitori a ti ṣẹ́ gbogbo olufẹ rẹ tutu,

Ka pipe ipin Jer 22

Wo Jer 22:20 ni o tọ