Jer 23:18 YCE

18 Nitori tali o duro ninu igbimọ Oluwa, ti o woye, ti o si gbọ́ ọ̀rọ rẹ̀? tali o kíyesi ọ̀rọ rẹ̀, ti o si gbà a gbọ́?

Ka pipe ipin Jer 23

Wo Jer 23:18 ni o tọ