Jer 23:7 YCE

7 Nitorina, sa wò o, ọjọ mbọ̀, li Oluwa wi, ti nwọn kì yio tun wipe, Oluwa mbẹ, ti o mu awọn ọmọ Israeli jade kuro ni ilẹ Egipti:

Ka pipe ipin Jer 23

Wo Jer 23:7 ni o tọ