Jer 25:18 YCE

18 Ani Jerusalemu ati ilu Juda wọnni, ati awọn ọba wọn pẹlu awọn ijoye, lati sọ wọn di ahoro, idãmu, ẹsin, ati egún, gẹgẹ bi o ti ri loni.

Ka pipe ipin Jer 25

Wo Jer 25:18 ni o tọ