Jer 26:12 YCE

12 Nigbana ni Jeremiah wi fun awọn ijoye ati gbogbo enia pe, Oluwa rán mi lati sọ asọtẹlẹ gbogbo ọ̀rọ ti ẹnyin gbọ́, si ile yi ati si ilu yi.

Ka pipe ipin Jer 26

Wo Jer 26:12 ni o tọ