Jer 27:19 YCE

19 Nitori bayi li Oluwa awọn ọmọ-ogun wi niti opó mejeji, ati niti agbada nla, ati niti ipilẹṣẹ, ati niti ohun-èlo iyokù ti o kù ni ilu yi.

Ka pipe ipin Jer 27

Wo Jer 27:19 ni o tọ