Jer 27:21 YCE

21 Nitori bayi li Oluwa awọn ọmọ-ogun, Ọlọrun Israeli wi, niti ohun-èlo ti o kù ni ile Oluwa, ati ni ile ọba Juda ati Jerusalemu.

Ka pipe ipin Jer 27

Wo Jer 27:21 ni o tọ