Jer 27:4 YCE

4 Ki o si paṣẹ fun wọn lati wi fun awọn oluwa wọn pe, Bayi li Oluwa awọn ọmọ-ogun, Ọlọrun Israeli wi, Bayi li ẹnyin o wi fun awọn oluwa nyin pe;

Ka pipe ipin Jer 27

Wo Jer 27:4 ni o tọ