Jer 30:19 YCE

19 Ati lati inu wọn ni ọpẹ́ ati ohùn awọn ti nyọ̀ yio ti jade: emi o si mu wọn bi si i, nwọn kì o si jẹ diẹ; emi o ṣe wọn li ogo pẹlu, nwọn kì o si kere.

Ka pipe ipin Jer 30

Wo Jer 30:19 ni o tọ