Jer 31:2 YCE

2 Bayi li Oluwa wi, Enia ti o sala lọwọ idà ri ore-ọfẹ li aginju, ani Israeli nigbati emi lọ lati mu u lọ si isimi rẹ̀.

Ka pipe ipin Jer 31

Wo Jer 31:2 ni o tọ