Jer 32:22 YCE

22 Ti iwọ si ti fun wọn ni ilẹ yi, eyiti iwọ bura fun awọn baba wọn lati fi fun wọn, ilẹ ti nṣàn fun wara ati oyin;

Ka pipe ipin Jer 32

Wo Jer 32:22 ni o tọ