Jer 32:39 YCE

39 Emi o si fun wọn li ọkàn kan, ati ọ̀na kan, ki nwọn ki o le bẹ̀ru mi li ọjọ gbogbo, fun rere wọn, ati ti awọn ọmọ wọn lẹhin wọn:

Ka pipe ipin Jer 32

Wo Jer 32:39 ni o tọ