Jer 33:15 YCE

15 Li ọjọ wọnni, ati li akoko na, emi o jẹ ki Ẹka ododo ki o hu soke fun Dafidi; ẹniti yio si ṣe idajọ ati ododo ni ilẹ na.

Ka pipe ipin Jer 33

Wo Jer 33:15 ni o tọ