Jer 33:18 YCE

18 Bẹ̃ni awọn alufa, awọn ọmọ Lefi, kì yio fẹ ọkunrin kan kù niwaju mi lati ru ẹbọ sisun, ati lati dana ọrẹ ohun jijẹ, ati lati ṣe irubọ lojojumọ.

Ka pipe ipin Jer 33

Wo Jer 33:18 ni o tọ