Jer 33:7 YCE

7 Emi o si mu igbèkun Juda ati igbèkun Israeli pada wá, emi o si gbe wọn ró gẹgẹ bi ti iṣaju.

Ka pipe ipin Jer 33

Wo Jer 33:7 ni o tọ