Jer 34:19 YCE

19 Awọn ijoye Juda, ati awọn ijoye Jerusalemu, awọn ìwẹfa, ati awọn alufa, ati gbogbo enia ilẹ na, ti o kọja lãrin ipin mejeji ẹgbọrọ malu na;

Ka pipe ipin Jer 34

Wo Jer 34:19 ni o tọ