Jer 36:13 YCE

13 Nigbana ni Mikaiah sọ gbogbo ọ̀rọ wọnni ti o ti gbọ́, fun wọn, nigbati Baruku kà lati inu iwe na li eti awọn enia.

Ka pipe ipin Jer 36

Wo Jer 36:13 ni o tọ