Jer 36:4 YCE

4 Nigbana ni Jeremiah pè Baruku, ọmọ Neriah; Baruku si kọ lati ẹnu Jeremiah gbogbo ọ̀rọ Oluwa ti o ti sọ fun u, sori iwe-kiká na.

Ka pipe ipin Jer 36

Wo Jer 36:4 ni o tọ