Jer 37:5 YCE

5 Ogun Farao si jade lati Egipti wá: nigbati awọn ara Kaldea ti o dótì Jerusalemu si gbọ́ iró wọn, nwọn lọ kuro ni Jerusalemu.

Ka pipe ipin Jer 37

Wo Jer 37:5 ni o tọ