Jer 4:10 YCE

10 Nigbana ni mo wipe, Ye! Oluwa Ọlọrun! nitõtọ iwọ ti tan awọn enia yi ati Jerusalemu jẹ gidigidi, wipe, Ẹnyin o ni alafia; nigbati idà wọ inu ọkàn lọ.

Ka pipe ipin Jer 4

Wo Jer 4:10 ni o tọ